Jump to content

Usoro Akpanusoh

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Usoro Akpanusoh jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ tí ó ń ṣojú àwọn ènìyàn Esit Eket / Ibeno ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ kẹfà ni Ìpínlẹ̀ Akwa Ibom . [1] [2]