Uzoma Nkem Abonta
Ìrísí
Uzoma Nkem Abonta jẹ́ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. O je ọmọ ile ìgbìmọ̀ aṣòfin ìjọba apapo nibi to ti ṣojú àgbègbè Ukwa East ati Ukwa West ti Ìpínlè Abia lati 2008 si 2011. A dibo fun labe ẹgbẹ́ òsèlú Peoples Democratic Party (PDP). Onigbagbo Nkwonta lo gba o. [1] [2] [3]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://www.vanguardngr.com/2021/09/nigeria-could-have-averted-endsars-if-we-had-procedural-petition-system-hon-nkem/
- ↑ https://thenewsguru.com/nigeria-news/tng-sunday-interview-theres-business-surrounding-covid-19-money-rep-nkem-abonta/
- ↑ https://dailypost.ng/2024/02/29/pdp-suspends-ex-abia-reps-member-abonta-for-alleged-anti-party-activities/