Jump to content

Véro Tshanda Beya Mputu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Véro Tshanda Beya
Ọjọ́ìbíVéronique Tshanda Beya Mbupu
Orílẹ̀-èdèDR Congo
Iṣẹ́Osere
Gbajúmọ̀ fúnFelicite (2017 film)

Véronique Tshanda Beya Mputu je osere ti o wa lati ilu Congo. Ogba ami eye Africa Movie Academy Award fun osere iwaju ti o dara julo fun ipa re ninu Felicite .

Igbesi aye ibẹrẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi Mputu osi dagba si ilu Kinshasa, eyi ti o je olu ilu Orílẹ̀-èdè Olómìnira Òṣèlú ilẹ̀ Kóngò [1]

Ni odun 2017, o ko pa ninu Felicite ni a se agbeyewo e ni 67th Berlin International Film Festival.[2] O ni ohun feran ipa na nitori pe ojuwe awon obinrin gege bi awon eniyan ti ole da duro, ti ko nilo iran lowo awon okunrin[3]O gba emi eye osere birin ti o da ra julo ni Africa Movie Academy Awards eleketala eleyi ti owaye ni Ilu Eko, Nàìjíríà.[4][5] Atu fun fiimu na ni ayewo gegebi Senegalese entry fun 90th Academy Awards, eleyi je fiimu akoko ti ilu senegal ti a fi kale fun ami eye na..[6][7] The Times juwe ipa re gegebi eyi ti ye ki ogba ami eye nitori oni igboya.[8]

Emerin ni o lo fun ayewo, oludari Alain Gomiso fe fun ni ipa ninu ere na.[9]

  1. https://web.archive.org/web/20170403132536/http://www.intothechic.com/17212/culture/4-choses-a-savoir-vero-tshanda-beya-mputu-rues-de-kinshasa-a-felicite/
  2. "Felicite". Berlinale. Retrieved 4 October 2020. 
  3. http://www.theupcoming.co.uk/2017/02/14/felicite-an-interview-with-star-vero-tshanda-beya-mputu/
  4. "Vero Tshanda wins best actress for “Félicité” at AMAA 2017". Trybe TV. Archived from the original on 7 November 2017. Retrieved 4 October 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Inyang, Ifreke (16 July 2017). "Full list of winners at 2017 AMAA". Daily Post. https://dailypost.ng/2017/07/16/full-list-winners-2017-amaa/. 
  6. Orubo, Daniel. "Here Are All The African Films Vying For 2018’s Foreign Language Oscar". konbini.com. Archived from the original on 18 April 2019. Retrieved 4 October 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. Thompson, Anne (14 December 2017). "The 2018 Foreign Language Oscar Shortlist: 9 Films, Many Snubs and Surprises". IndieWire. Retrieved 4 October 2020. 
  8. Maher, Kevin (10 November 2017). "Film review: Félicité". The Times. https://www.thetimes.co.uk/article/film-review-felicite-0zbmjm7l7. 
  9. "4 choses à savoir sur Véro Tshanda Beya Mputu, des rues de Kinshasa à « Félicité »" [4 things to know about Véro Tshanda Beya Mputu, from the streets of Kinshasa to "Félicité"]. intothechic.com (in French). 29 March 2017. Archived from the original on 3 April 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)