Jump to content

Vasco da Gama

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Vasco da Gama
Ọjọ́ìbí1460 or 1469
Sines or Vidigueira, Alentejo, Portugal
Aláìsí24 December 1524 (aged 54-64)
Kochi, India
Iṣẹ́Explorer, Governor of Portuguese India
Signature

Vasco da Gama, 1st Count of Vidigueira (Pípè ni Potogí: [ˈvaʃku dɐ ˈɡɐmɐ]) (c. 1460 tabi 1469 – 24 December 1524) je oluwakiri ara Portugal, ikan ninu awon to yori si rere julo ni Igba Awari ati adari oko ojuomi akoko to lo taara lati Europe de India.