Vatiswa Ndara
Ìrísí
Vatiswa Ndara | |
---|---|
Ìbí | 28 Oṣù Kẹ̀sán 1970 Mthatha, South Africa |
Iṣẹ́ | Actress, Broadcaster, Voice Artist, Host, Social Media Personality |
Vatiswa Ndara (bíi ni ọjọ́ kejìdínlógbọ̀n oṣù kẹsàn-án ọdún 1970) jẹ́ òṣèré àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà.[1][2] Wọn bí sì ìlú Mthatha ni ilẹ̀ Eastern Cape. Ní ọdún 1994, ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí oníróyìn ni orí rádíiò Transkei. Ó ti ṣiṣẹ́ pẹlu awọn ilé iṣẹ́ rádíiò bíi Radio Bob, Kaya Fm, Metro Fm, 5Fm àti Highveld Stereo. Ó bẹ̀rẹ̀ eré ṣíṣe nígbà tí wón ní kí ó kó ipa Ma'mfundisi nínú eré Generations. Ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹwàá ọdún 2019, ó kọ lẹ́tà sì Nathi Mthethwa tí ó jé aṣojú ìjọba lórí ọ̀rọ̀ àṣà àti ìṣe, lẹ́tà náà sọ nípa bí àwọn ilé iṣẹ́ Connie Ferguson àti Shona Ferguson ṣe ń fi ìyà jẹ àwọn òṣèré.[3][4][5]
Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Generations
- Gaz'lam
- Salvation[6]
- Nomzamo
- Home Affairs
- Society
- Shooting Stars
- 90 Plein Street
- Ihawu le Sizwe
- Muvhango
- Igazi
- Ithemba
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Vatiswa Ndara | TVSA". www.tvsa.co.za. Retrieved 2019-12-17.
- ↑ "Vatiswa Ndara: The Fergusons were caught in the crossfire". TimesLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-17.
- ↑ "Veteran actress Vatiswa Ndara exits Muvhango and rebukes rumours". The South African (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-10-22. Retrieved 2019-12-17.
- ↑ "Vatiswa Ndara confirms Muvhango exit - but denies she was 'difficult'". SowetanLIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-17.
- ↑ "Vatiswa Ndara and other local actors have good reason to demand a better deal | IOL News". www.iol.co.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-17.
- ↑ "Getting to know Vatiswa Ndara... or not | IOL Entertainment". www.iol.co.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-12-17.