Jump to content

Veli Mitova

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Veli Mitova
OrúkọVeli Mitova
Ìgbà21st-century philosophy
AgbègbèWestern philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Analytic
Ìjẹlógún ganganepistemology, moral epistemology, epistemic decolonisation

Veli Mitova jẹ́ amòye ti ìlú South Africa. Ó sì tún jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n nínú ẹ̀kọ́ ìmòye àti olùdarí African Centre for Epistemology àti Philosophy of Science (ACEPS) ní University of Johannesburg.[1] Ó gbajúmọ̀ fún oṣẹ́ rẹ̀ lórí epistemic decolonization àti àwọn ìdí tí ìgbàgbọ́ fi wáyé, ní pàtàkì sí ìwòye rẹ̀ nínú truthy psychologism.[2][3][4][5][6]

Àwọn ìwé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Believable Evidence, Veli Mitova, Cambridge University Press, 2017
  • The Factive Turn in Epistemology, Veli Mitova (ed.), Cambridge University Press, 2018

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "African Centre for Epistemology and Philosophy of Science". University of Johannesburg (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 
  2. Dewhurst, Tess (4 May 2019). "Believable Evidence". Philosophical Papers 48 (2): 321–325. doi:10.1080/05568641.2019.1616605. ISSN 0556-8641. 
  3. Eslami, Seyyed Mohsen (3 April 2018). "The long way to "extreme psychologism"". South African Journal of Philosophy 37 (2): 171–177. doi:10.1080/02580136.2018.1441644. ISSN 0258-0136. 
  4. "Prof Velislava Mitova" (PDF). www.uj.ac.za. Archived from the original (PDF) on 2019-12-28. Retrieved 2024-05-13. 
  5. Whiting, Daniel (21 August 2018). "Review of The Factive Turn in Epistemology". Notre Dame Philosophical Reviews. ISSN 1538-1617. https://ndpr.nd.edu/news/the-factive-turn-in-epistemology/. 
  6. Gregory, Alex (29 April 2012). "Review of Reasons for Belief". Notre Dame Philosophical Reviews. ISSN 1538-1617. https://ndpr.nd.edu/news/reasons-for-belief/.