Venus and Adonis (Veronese, Madrid)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Venus and Adonis jẹ́ àwòrán kíkùn  tí olóògbé Paolo Veronese, ayàwòrán ọmọ orílẹ̀ èdè Italy yà ní ọdún 1580, tí ó wà ní Museo del Prado ní Madrid báỳí. Wọ́n fẹ àwòrán ti tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ lọ́wọ́ òkè ní ọrundún méjìdínlógún sẹ́yìn. Wọ́n yọ abala èyí tí wọ́n fi kun kúrò lati dáapadà (c. 1988) kí iṣẹ́ yì lé lè padà sí oníbùú.

Níṣókí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Venus y Adonis (Veronese).jpg Wọ́n mú àkọ́lé lati Ovid. Ó sàfihàn ọlọ́dẹ Adonis tí ó sùn sí orí itan Venus. Eros wà níwájú ẹ̀ pẹ̀lú ajá ọdẹ kan. Wọ́n ṣe àfihàn Cupid níbi tí ó ti ń gbìyànjú lati má jẹ́ kí ajá yìí dẹgbó nítorí pé Venus ti sàsọtẹ́lẹ̀ wípé Adonis ma ́a kú ní àkókò ọdẹ. Àlà ilẹ̀ wà ní abẹ́lẹ̀ pẹ́lú àwọ̀ ewé àti ojú ọ̀run tó búlúù.

Àwọ́n ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]