Vera Okolo
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Vera Okolo | ||
Ọjọ́ ìbí | 5 Oṣù Kínní 1985 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
Ìga | ft 0 in (0.00 m) | ||
National team | |||
Nigeria women's national football team | |||
† Appearances (Goals). |
Vera Okolo jẹ ọkan lara agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 5, óṣu January ni ọdun 1985. Arabinrin naa ṣere fun team awọn obinrin ilẹ naigiria ti national lori bọọlu[1][2].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Vera ti ṣere fun Delta Queens ni ere idije awọn obinrin ilẹ naigiria[3].
- Arabinrin naa ti wa lara team ti o kopa ninu olympic to waye ni ọdun 2004[4].
- Vera ti jẹ àṣoju fun super falcons ni ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2004 to waye ni ilẹ south afirica[5]
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://int.soccerway.com/players/vera-okolo/291451/
- ↑ https://www.olympedia.org/athletes/103011
- ↑ https://allfamousbirthday.com/vera-okolo/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensolympic/athens2004/teams/1882893
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-29. Retrieved 2022-05-29.