Jump to content

Victor Oladokun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Victor Oladokun
Ọjọ́ìbíVictor Bandele Oladokun
26 Oṣù Kẹta 1958 (1958-03-26) (ọmọ ọdún 66)
England
Orílẹ̀-èdèNigerian
British
Ẹ̀kọ́Regent University
Obafemi Awolowo University
Iṣẹ́Broadcaster, TV host, journalist, media consultant
Ìgbà iṣẹ́1990–present
OrganizationAfrica Development Bank Group
Gbajúmọ̀ fúnTurning Point, CBN World News

Victor Oladokun (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Victor Bandele Oladokun) ó jẹ́ oníròyìn, àti elétò ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ ní Nigeria àti united kingdom. Ó jẹ́ Olùdarí fún ìbánisọ̀rọ̀ àti ìbáṣepọ̀ àwọn ará ilẹ̀ òkèrè African Development Bank AFDB [1][2] ó sì tún jẹ́ aṣagbátẹrù, àti olùgbàlejò fún gbajúgbajà ètò magasíìnì lórí amóhùnmáwòrán ti gbogbo àgbáyé. CBN World News and Turning Point on the Christian Broadcasting Network CBN.[3]

  1. "UNGA 2019: Women are "Africa's tigers" says Congolese First Lady as African Development Bank touts $3bn fund | African Development Bank - Annual Meetings 2020". am.afdb.org. 
  2. Clarke, Justice R. (6 June 2019). "Liberia: AfDB Sure Media Can Help Shape Mindset for Sustainable Development". allAfrica.com. 
  3. "Victor Oladokun". 7 August 2017. Archived from the original on 29 March 2023. Retrieved 29 March 2023.