Jump to content

Vida Opoku

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Vida Opoku
Personal information
Ọjọ́ ìbí15 Oṣù Kejìlá 1997 (1997-12-15) (ọmọ ọdún 27)
Ìga1.67m
Playing positionDefender
Club information
Current clubOlympique Marseille Ladies(GHA)
National team
Ghana women's national football team
† Appearances (Goals).
‡ National team caps and goals correct as of 14 September 2019


Vida Opoku jẹ agabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 15, óṣu December ni ọdun 1997. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin Olympique Marseille gẹ̀gẹbi defender.

  • Vida kopa ninu Cup FIFA U-17 awọn obinrin agbaye ti ọdun 2012, 2014 ati 2016.