Jump to content

Viktor Suhorukov

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Viktor Suhorukov
Ọjọ́ìbíВиктор Иванович Сухоруков
10 Oṣù Kọkànlá 1951 (1951-11-10) (ọmọ ọdún 72)
Mọsko oblast, Ìsọ̀kan Sófìẹ̀tì
Orílẹ̀-èdèRọ́síà Rọ́síà
Iléẹ̀kọ́ gígaGITIS (1978)
Iṣẹ́òṣèré
Ìgbà iṣẹ́1974–present

Viktor Suhorukov (Oṣù Kọkànlá ọjọ́ kẹwá, 1951) jẹ́ òṣèré ará Russia. Ó ti kópa nínú fíìmù àti amóùn-máwòran bíi àádọ́ta láti ọdún 1974.[1]

Díẹ̀ nínú àwọn eré tí ó ti kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Happy Days (1991)
 • The Year of the Dog (1994)
 • The Castle (1994)
 • All My Lenins (1997)
 • Brother (1997)
 • Brother 2 (2000)
 • Antikiller (2002)
 • Poor Poor Paul (2003)
 • Goddess: How I fell in Love (2004)
 • Graveyard Shift (2005)
 • Dead Man's Bluff (2005)
 • The Island (2006)
 • Silent Souls (2010)
 • Furtseva (12-part Russian TV series) (2011)
 • Ivan Tsarevich and the Gray Wolf (2011)
 • Orlean (2015)
 • Paradise (2016)

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. "Festival de Cannes: Happy Days". festival-cannes.com. Retrieved 16 August 2009.