Viktor Yanukovych
Ìrísí
Viktor Yanukovych Віктор Янукович | |
---|---|
President of Ukraine | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 25 February 2010 | |
Alákóso Àgbà | Yulia Tymoshenko Oleksandr Turchynov (Acting) Mykola Azarov |
Asíwájú | Viktor Yushchenko |
Prime Minister of Ukraine | |
In office 21 November 2002 – 7 December 2004 | |
Ààrẹ | Leonid Kuchma |
Asíwájú | Anatoliy Kinakh |
Arọ́pò | Mykola Azarov (Acting) |
In office 28 December 2004 – 5 January 2005 | |
Ààrẹ | Leonid Kuchma |
Asíwájú | Mykola Azarov (Acting) |
Arọ́pò | Mykola Azarov (Acting) |
In office 4 August 2006 – 18 December 2007 | |
Ààrẹ | Viktor Yushchenko |
Asíwájú | Yuriy Yekhanurov |
Arọ́pò | Yulia Tymoshenko |
Governor of Donetsk Region | |
In office 14 May 1997 – 21 November 2002 | |
Asíwájú | Volodymyr Sherban |
Arọ́pò | Anatoliy Blyzniuk |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 9 Oṣù Keje 1950 Yenakiieve, Ukrainian SSR, Soviet Union (now Ukraine)[1] |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Independent (2010–present) |
Other political affiliations | Communist Party of the Soviet Union (1980–1991)[2] Party of Regions (2003–2010) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Lyudmilla Oleksandrivna |
Àwọn ọmọ | Olexander Viktor |
Alma mater | Donetsk Polytechnic Institute |
Profession | Mechanical engineer |
Signature | |
Website | President's website |
Viktor Fedorovych Yanukovych (Ukrainian: Віктор Федорович Янукович (ìrànwọ́·ìkéde) Viktor Fedorovyč Janukovyč; Rọ́síà: Виктор Фёдорович Янукович) (ojoibi July 9, 1950, Yenakiieve, Donetsk Oblast) ni Aare ekerin orile-ede Ukraine lati 25 February, 2010.
Yanukovych je Gomina igberiko Donetsk Oblast lati 1997 de 2002. Yanukoych tun wa ni ipo Alakoso Agba ile Ukraine lemeji lati November 21, 2002 de December 31, 2004 labe Aare Leonid Kuchma ati lati August 4, 2006 titi de December 18, 2007 labe Aare Viktor Yushchenko, to je alatako re ninu idiboyan Aare 2004 nibi to gba ipo keji.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedLGAWYu
- ↑ "Yanokovich, Viktor". Lentapedia (in Russian). Lenta.ru. Retrieved 2009-06-13.