Vilma Espin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Vilma Espín
Vilma Espin nígbà tí ó sì jẹ́ ọ̀dọ́bìnrin
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1930-04-07)7 Oṣù Kẹrin 1930
Aláìsí18 June 2007(2007-06-18) (ọmọ ọdún 77)
ẸbíFidel Castro (brother-in-law)
Jose Espín (father)
Margarita Guillois (mother)
Nilsa Espín (sister)
Iván Espín (brother)
Sonia Espín (sister)
José Espín (brother)
Àwọn ọmọDeborah Castro Espín
Mariela Castro Espín
Nilsa Castro Espín
Alejandro Castro Espín
AwardsLenin Peace Prize 1977-78
{{{blank1}}}Raúl Castro

Vilma Lucila Espín Guillois (tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹrin ọdún 1930 tí ó sì kú ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹfà ọdún 2007) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Kuba bẹ́ẹ̀ sì ni ó tún jẹ́ ìyàwó Raul Kastro Ààrẹ ilẹ̀ Kuba. Ó kó ipa tí ó ṣe kókó nínú ìjà gbára ilé Cuba.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]