Jump to content

Vincent Desmond

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Vincent Desmond
Ọjọ́ìbíVincent Desmond
Orílẹ̀-èdèNàìjíríà
Iṣẹ́Human Rights Activist, popular culture journalist, editor, writer, queer Advocate
Gbajúmọ̀ fúnHuman Rights Activism, LGBTIQ Advocacy, Pop Culture, Journalism,
TitleHuman Rights Activist, Culture journalist, Editor-in-Chief
Websitehttps://www.desmondvincent.me/

Vincent Desmondjẹ́ oníṣẹ́ ìròyìn tí ó jọ mọ́ àṣà, ònkọ̀tàn, olóòtú ati olùpolongo ẹ̀tọ́ àwọn LGBTQ tí ó fi Ìpínlẹ̀ Èkó ṣe ibùgbé ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Òun ni olóòtú àgbà fún ìwé-ìròyìn olóṣooṣù nípa oge ṣíṣe kan tí wọ́n pe ní A Nasty Boy tí ọ̀gbẹ́ni Richard Akuson tí ó jẹ́ oníṣẹ́ ìròyìn àti amòfin da sílẹ̀ ní ọdún 2017.[2][3][4]

Vincent ti ke onírúurú àpilẹ̀kọ fún àwọn ìwé ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde, ati ti orí ẹ̀rọ ayélujára tí wọ́n ṣe àgbéyẹwò ati akọsílẹ̀ nípa ẹ̀yà ara ìbálòpọ̀ ọmọnìyàn, àṣà tó gbajúmọ̀, ige, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.[5]

Ní ọdún 2020, ó fi ìmọ̀sílára rẹ̀ hàn lórí ọmọ bíbí àti jíjẹ́ òbí lórí ìkànì micro blogging site; níbi tí ó ti sọ wíp “gẹ́gẹ́ bí ìròrí tèmi, kí á ma bímọ jẹ́ ìwà ìmọ̀ tara ẹni nìkan.

ìdí ni wípé òbí ń bí odidi ọmọ ènìyàn míràn wá sáyé láti wá ma kópa nínú làásìgbò ayé. Níotí kí ni? Ṣé nítorí kí ó lè wá ma jà sí ẹ̀tọ́? Ṣé nítorí wípé ó tó ni tàbí ó tọ́?" [6]

Awọn amì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn àjọ TIERS Nigeria fun ní àmì-ẹ̀yẹ Young Trailblazer of the Year ní ọdún 2020 .[7][5][8]

Wọ́n yàn án mọ́ àwọn tí wọ́n fẹ́.fún ní amì-ẹ̀yẹ “The 150 Most Interesting Nigerians in Culture in 2019" láti ọwọ́ RED Media Africa.[9]

Àwọn ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Vincent Desmond". runner (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-04. 
  2. "A Nasty Boy Founder Richard Akuson Announces Vincent Desmond as New Editor & Publisher | Exclusive & Interview". Brittle Paper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-01-02. Retrieved 2021-09-04. 
  3. "'A Nasty Boy' Is the Gender-Noncomforming Magazine Turning Nigerian Conservatism On Its Head". OkayAfrica (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-09-14. Retrieved 2021-09-04. 
  4. Wheeler, André-Naquian (2017-08-01). "'a nasty boy' magazine is challenging what masculinity means in nigeria". i-D (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-04. 
  5. 5.0 5.1 "Hidden Gems: Vincent Desmond Isn’t Afraid To Tell The Stories Others Won’t". MoreBranches (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-02-13. Retrieved 2021-09-04. 
  6. Dace (2020-05-11). "“Having kids is a very selfish thing” – Nigerian gay writer, Vincent Desmond". TobiVibes (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-04. 
  7. TIERsadmin (2020-10-30). "Nominate Persons for the 2020 Freedom Awards". TIERS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-09-04. Retrieved 2021-09-04. 
  8. "The 2020 Freedom Awards Honour LGBTQ & Feminist Advocates". Open Country Mag (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-12-26. Retrieved 2021-09-04. 
  9. Editor (2020-01-01). "Chude Jideonwo’s list of the 150 most interesting people in the culture [2019] » YNaija". YNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-09-04.