Vivian Mensah
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 13 Oṣù Kẹfà 1972 | ||
Playing position | Forward | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
La Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Vivian Mensah jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ 13, óṣu June ni ọdun 1972. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin La gẹgẹbi forward.
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Vivian kopa ninu Cup FIFA awọn obinrin agbaye ti ọdun 1999.