Vivienne Roumani
Ìrísí
Vivienne Roumani | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Vivienne Roumani 1950 (ọmọ ọdún 73–74) Benghazi, Libya |
Orílẹ̀-èdè | Libyan |
Iṣẹ́ | Actress, choreographer, composer |
Ìgbà iṣẹ́ | 1995–present |
Àwọn ọmọ | Aryeh Bourkoff |
Parent(s) |
|
Website | http://vivienneroumani.com |
Vivienne Roumani-Denn (tí wọ́n bí ní ọdún 1950) jẹ́ olùdarí eré àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Líbyà.[1] Ó gbajúmọ̀ fún dídarí eré The Last Jews of Libya àti Out of Print.[2]