Jump to content

Wẹ̀rẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
A home of a mad man in Cross River State

Wèrè jẹ́ ènìyàn kan tí kò gbádùn tàbí tí a lẹ̀ wí pé kò mọ ohun tó ń ṣe mọ.[1]

ilée wèrè jẹ́ ilée kan tí ó jẹ́ wí pé oríṣiríṣi nǹkan ni ènìyàn máa ń bá níbẹ̀. Àwọn nǹkan bíi pàǹtí sáábà máa ń wà níbẹ̀. Àwọn wèrè máa ń sáábà kó àwọn pàǹtí àti nǹkan mìíràn láti ibi tí wọ́n bá ń gbà jọká lọ sí ilée wọn. Ibẹ̀ dẹ̀ lọ máa ń gbé láìní wọ́n lára.[2]

  1. "Definition of mad". www.dictionary.com. 2019-03-12. Retrieved 2022-05-21. 
  2. "MAD - Meaning & Definition for UK English". Lexico Dictionaries. Archived from the original on 2022-05-21. Retrieved 2022-05-21.  Text "English" ignored (help)