Waino Aaltonen

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Wäinö Aaltonen

Waino Aaltonen je onise ona amo omo ile Finlandi. Oníṣé ọnà ara, finland ni èyí. Wọ́n bí i ní 1894. Ó kú ní 1966 Ó ń gbégilére. Ó ń kun nǹkan òun ni ó kọ́kọ́ ṣe agbétẹrù pé kí a máa fi òkúta gbẹ́ nǹkan.