Jump to content

Waris Dirie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Waris Dirie
Dirie in 2018
Ọjọ́ìbí1965 (ọmọ ọdún 58–59)
Galkayo, Somalia
Iṣẹ́Model, social activist, author, actress, UN Special Ambassador (1997–2003)
TitleChevalier of the Légion d'honneur

Waris Dirie (bíi ni ọdún 1965) jẹ́ mọ́dẹ́lì, òṣèré àti ajìjàgbara lórílẹ̀-èdè Uganda

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Dirie ní ọdún 1965, ó ṣì jẹ́ ìkan lára àwọn ọmọ méjìlá tí àwọn òbí rẹ bí. Nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹ́tàlá, ó sá kúrò nílé nítorí àwọn ẹbí rẹ̀ ní kí ó fẹ́ arákùnrin kan tí ó jẹ́ ọmọ ọgọ́ta ọdún. Wọ́n mu lọ sí ìlú London láti lọ ṣe ọmọ ọ̀dọ̀.[1][2]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 1987, ó kópa nínú eré The Living Daylights èyí tí James Bond gbé kalẹ̀. Ní ọdún 2015, Dirie sọ̀rọ̀ nípa bí wọn ṣe ṣíṣe abẹ fún ohun nígbà tí òhun wà ní ọmọ ọdún márùn-ún.[3] Ní ọdún 1998, óun àti Cathleen Miler jọ kọ ìwé Desert Flower.[4] Ní ọdún 2004, ó gbà àmì ẹ̀yẹ World Social Award láti ọ̀dọ̀ Women's World Award Gala ní ìlú Hamburg lórílẹ̀-èdè Germany[5]. Ní ọdún 2007, Al Jazeera pe Warris Dirie láti wá sọ̀rọ̀ lórí Female Genital Mutilation.[6] Ní ọdún 2009, wọ́n ṣe eré Desert Flower lórí ìwé tí Waris tí kọ.[7][8][9] Ní ọdún 2010, àwọn African Union fi ṣe àmbásẹ́dọ̀ fún àlàáfíà àti àbò ní ilẹ̀ Áfríkà.[10] Ní oṣù kìíní ọdún 2009, Dirie di ìkan lára àwọn olùdásílẹ̀ ẹgbẹ́ PPR Foundation for Women's Dignity and Rights[11]. Lára àwọn ẹgbẹ́ ajìjàgbara fún àwọn obìnrin tí ó wà ni Stop FGM Now[12], Together for African Women[13],End FGM[14][15][16][17][18]. Ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kẹsàn-án ọdún 2013, Dirie ṣí ilé ìwòsàn The Desert Flower Center[19][20][21][22][23]. Ní ọjọ́ keje, oṣù kẹta ọdún 2019, wọn sọ pé wọn má kọ orin nípa ìtàn ayé rẹ̀.[24] Ní ọjọ́ kẹjìlélógún oṣù kejì ọdún 2020, wọn gbé orin náà jáde.[25][26]

Àmì Ẹ̀yẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Woman of the Year Award (2000) láti ọ̀dọ̀ Glamour magazine.[27]
 • Corine Award (2002) .[28]
 • Women's World Award (2004) .[29]
 • Chevalier de la Légion d’Honneur (2007).[30]
 • Prix des Générations (2007) láti ọ̀dọ̀ World Demographic Association.[31]
 • Martin Buber Gold Medal láti ọ̀dọ̀ Euriade Foundation (2008).[32].
 • Gold medal of the President of the Republic of Italy (2010) .[33]
 • Thomas Dehler Prize (2013) [34]
 • International Freedom Prize (2014) [35]
 • Women for Women Award (2017), awarded in Vienna by the magazine "look![36]
 • Donna dell'Anno (2018) in Italy[37]
 • ~ Million Chances Award (2018) [38]
 • Sunhak Peace Prize (2019).[39][40]

Ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Dirie di ọmọ orílẹ̀ èdè Australia ní oṣù kẹta ọdún 2005.[41]

Àwọn Ìtọ́kàsi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 1. Stellan Consult Limited (2008). "Desert Flower". Parents (265–270): 76. 
 2. Mary Zeiss Stange, Carol K. Oyster, Jane E. Sloan, ed. (2011). Encyclopedia of Women in Today's World, Volume 1. SAGE. p. 402. ISBN 1412976855. 
 3. Wendlandt, Astrid (8 March 2010). "International Women's Day absurd says supermodel". Reuters. https://www.reuters.com/article/2010/03/08/us-waris-dirie-women-idUSTRE62755A20100308. Retrieved 2 April 2014. 
 4. "DESERT FLOWER". Kirkus Reviews. Retrieved 13 July 2018. 
 5. "Die WOMEN´S WORLD AWARDS-Preisträgerinnen 2004 stehen fest". OTS.at. 
 6. https://www.dailymotion.com/video/xq6ncg
 7. Katja Hofmann (2008-02-09). "Model Liya Kebede to star in 'Flower'". Variety.com. https://www.variety.com/article/VR1117980606.html?categoryid=13&cs=1&nid=2564/. Retrieved 2014-04-17. 
 8. "Wüstenblume – A-Z – Filme – Österreichisches Filminstitut". Filminstitut.at. Retrieved 2012-02-20. 
 9. "Desert Flower". Retrieved 10 July 2017. 
 10. "AU appointed peace ambassadors for Africa « Afronline – The Voice Of Africa". Archived from the original on 2022-11-25. Retrieved 2020-11-29. 
 11. "PPR Foundation for Women's Rights and Dignity". Ppr.com. 2014-02-21. Retrieved 2014-04-17. 
 12. "Heymann Brandt De Gelmini engagiert sich gegen Genitalverstümmelung". www.horizont.net. 
 13. ""Wüstenblume"-Autorin Waris Dirie präsentiert Dessous für Mey". www.horizont.net. 
 14. a brief period in %5b%5bChicago%5d%5d, Illinoisfgm-rates-are-rising/ "Waris Dirie: Europe's FGM rates are rising and we must fight it" Check |url= value (help). 
 15. "Supported by iF projects 2019". iF WORLD DESIGN GUIDE. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
 16. "Waris Dirie, Coco de Mer, and Rankin Are Fighting for Women's Rights". Daily Front Row. March 7, 2019. 
 17. "Model And Activist Waris Dirie Calls On Women To Join The Fight To End FGM". British Vogue. 
 18. "Comeback von Waris Dirie: Musical und Dessous im Namen der "Wüstenblume"". kurier.at. 
 19. "Quel honneur! Le Président Français au Centre Fleur du Désert - Desert Flower Foundation". www.desertflowerfoundation.org. 
 20. "Desert Flower Center Waldfriede, DFC Berlin". www.dfc-waldfriede.de. 
 21. "Abgeordnetenhaus von Berlin – Louise-Schroeder-Medaille 2016". www.parlament-berlin.de. 
 22. "Desert Flower Foundation increases global awareness about FGM, makes impact in West Africa". Archived from the original on 2021-06-22. Retrieved 2020-11-29. 
 23. Voss, Huberta von (March 16, 2019). "Die Wüste bebt" – via www.welt.de. 
 24. "Model turned activist Waris Dirie says world is ignoring the crime...". March 7, 2019 – via www.reuters.com. 
 25. https://www.sueddeutsche.de/kultur/musik-gaensehautmomente-beim-musical-wuestenblume-dpa.urn-newsml-dpa-com-20090101-200223-99-32980
 26. https://www.suedostschweiz.ch/kultur-musik/2020-02-23/wuestenblume-waris-diries-leben-als-musical-in-st-gallen
 27. "Waris Dirie: ‘Female genital mutilation is pure violence against girls’". Retrieved 10 July 2017. 
 28. Corine Award Archived 2019-04-25 at the Wayback Machine. Corine Award 2002 Waris Dirie for Desert Dawn
 29. "Women's World Awards". Womensworldawards.com. Archived from the original on 2019-02-17. Retrieved 2014-04-17. 
 30. Communiqué de la Présidence de la République annonçant la remise de décoration par M. Nicolas SARKOZY, Président de la République July 12, 2007.
 31. "World Demographic Association". Archived from the original on 2009-06-04. Retrieved 10 July 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
 32. Martin Buber Foundation Archived 2014-04-09 at the Wayback Machine. Martin Buber Gold Medal 2007 for Waris Dirie
 33. "La top model somala Waris Dirie: "Chiedo aiuto al Papa per salvare le bambine africane dall'infibulazione" | Blog Quotidiano.net". Club.quotidiano.net. Archived from the original on 2011-07-24. Retrieved 2012-02-20. 
 34. "Thomas-Dehler-Preis 2013 geht an Waris Dirie". Die Presse. July 8, 2013. 
 35. "Ex-supermodel Waris Dirie says FGM can end in her lifetime". January 29, 2015 – via www.reuters.com. 
 36. ""Auch in Österreich ein Problem": Kämpferin für Rechte von Mädchen". Die Presse. November 29, 2017. 
 37. "Waris Dirie, Isoke Aikpitanyi e Margarita Meira: sono tre le Donne dell’anno 2018 - La Stampa". lastampa.it. March 16, 2018. 
 38. Meissner, Paulina (November 7, 2018). "Schwarzkopf "Million Chances Award": "Wüstenblume" Waris Dirie wird ausgezeichnet". Express.de. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
 39. Committee, The Sunhak Peace Prize. "The Sunhak Peace Prize for 2019 Awarded to Waris Dirie and Dr. Akinwumi Ayodeji Adesina". www.prnewswire.com. 
 40. "Der in Seoul veranstaltete Sunhak Peace Prize für 2019 wurde an Akinwumi Ayodeji Adesina und Waris Dirie verliehen". OTS.at. 
 41. NACHRICHTEN, n-tv. "Diries neue Staatsbürgerschaft". n-tv.de.