Warner Baxter

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Warner Baxter
Ọjọ́ìbíWarner Leroy Baxter
(1889-03-29)Oṣù Kẹta 29, 1889
Columbus, Ohio,
Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
AláìsíMay 7, 1951(1951-05-07) (ọmọ ọdún 62)
Beverly Hills, California,
Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà
Iṣẹ́Òṣèré
Ìgbà iṣẹ́1914–1950
Olólùfẹ́Viola Caldwell (1911-1913)
Winifried Bryson (1918–1951)

Warner Leroy Baxter (March 29, 1889 – May 7, 1951) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà, tó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ bíi The Cisco Kid nínú filmu In Old Arizona (1929), èyí tó gba Ẹ̀bùn Akádẹ́mì fún Ọkùnrin Òṣèré Tódárajùlọ ní ọdún 1928-1929.[1]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Cliff Aliperti (29 March 2010). "Warner Baxter-A Brief Biography". Things and Other Stuff. Retrieved 2011-11-16.