Wasila Diwura-Soale
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 1 Oṣù Kẹ̀sán 1996 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Tamale, Ghana | ||
Ìga | 1.57 m | ||
Playing position | Midfielder | ||
Youth career | |||
Hasaacas Ladies | |||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2012–2015 | Hasaacas Ladies]] | ||
National team | |||
2012–2013 | Ghana women's national under-17 football team | 6 | (0) |
2014–2016 | Ghana women's national under-20 football team | 6 | (1) |
2016– | Ghana women's national football team | 3 | (0) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 14 November 2021. † Appearances (Goals). |
Wasila Diwura-Soale jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ ghana ti a bini ọjọ akọkọ, óṣu september ni ọdun 1996. Agbabọọlu naa ṣere fun awọn ọdọmọbinrin Hasaacas gẹgẹbi midfielder[1].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Wasila kopa ninu Cup agbaye ti ọdun 2012[2].