Wendy Achieng
Ìrísí
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Wendy Ann Achieng Asol | ||
Ọjọ́ ìbí | 12 Oṣù Kẹ̀sán 1993 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Bungoma, Kenya | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Spedag | |||
National team | |||
Kenya women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Wendy Achieng jẹ agbabọọlu lobinrin ilẹ kenya ti a bini 12, óṣu september ni ọdun 1993. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender[1][2][3].
Àṣeyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Wendy kopa ninu Cup awọn obinrin ilẹ afirica ti agbaye to waye ni ọdun 2016[4].