Agbègbè Apáìwọ̀òrùn Nàìjíríà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Western Region, Nigeria)
Agbègbè Apá-ìwọ̀-oòrùn Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tàbí Western Region fi ìgbà kan jẹ́ apá ìṣèlú ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú olú-ìlú ní Ìbàdàn. Wọ́n dá a sílẹ̀ ní ọdún 1930 lábẹ́ ìjọba amúnisìn àwọn ará Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, ó sì wà títí di ọdún 1967.
Àyọkà tó bára mu
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |