Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 10 Oṣù Kejìlá
Appearance
- 1799 – Fránsì gba ìwọ̀n mítà (metre) gẹ́gẹ́ bíi òsùwọ̀n ìgùn fún àlòsisẹ́.
- 1817 – Mississippi di ìpínlẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà 20k.
- 1901 – Àwọn Ẹ̀bùn Nobel àkọ́kọ́ jẹ́ fífisọrẹ.
- 1948 – Ilé Ìgbìmọ̀ Gbogbogbòò Ìṣọ̀kan àwọn Orìlẹ̀-èdè gba Ìkéde Akáríayé fún àwọn Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn fún lílò.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1815 – Ada Lovelace, English mathematician (d. 1852)
- 1924 – Michael Manley, Prime Minister of Jamaica (d. 1997)
- 1934 – Howard Martin Temin, American geneticist, Nobel laureate (d. 1994)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1896 – Alfred Nobel, Swedish inventor and founder of the Nobel Prize (b. 1833)
- 1936 – Luigi Pirandello, Italian writer, Nobel laureate (b. 1867)
- 2005 – Richard Pryor, aláwàdà ará Amẹ́ríkà (ib. 1940)