Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 18 Oṣù Kẹfà
Ìrísí

- 1815 – Napoleonic Wars: Napoleon Bonaparte jẹ́ bíborí nínú Ìjà Waterloo.
- 1953 – Ìparẹ́ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Egypti,àṣẹọba rọ́pò rẹ̀.
- 1983 – Ètò Ọkọ̀-àlọbọ̀: STS-7, Arìnlófurufú Sally Ride di obìnrin ará Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ nínú òfurufú.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1929 – Jürgen Habermas, amòye àti aṣiṣẹ́aláwùjọ ará Jẹ́mánì
- 1931 – Fernando Henrique Cardoso, Ààrẹ ilẹ̀ Brasil
- 1942 – Thabo Mbeki (fọ́tò), Ààrẹ ilẹ̀ Gúúsù Áfríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1858 – Rani Lakshmibai, oníjà òmìnira ará Índíà (ib. 1835)
- 1936 – Maxim Gorky, olùkọ̀wé ará Rọ́síà
- 1971 – Paul Karrer, aṣiṣẹ́ògùn ará Swítsálandì (ib. 1889)