Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀sán
Appearance
Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀sán: Ojo ilominira ni Uzbekistan (1991)
- 1939 – Jemani Nazi rolu Poland ni Wieluń ati Westerplatte, eyi lo bere Ogun Agbaye Keji ni Europe.
- 1961 – Ogun Igbominira Eritrea bere gangan nigbati Hamid Idris Awate yinbon mo olopa kan ni Ethiopia.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1947 – Al Green, American politician
- 1962 – Ruud Gullit, Dutch footballer
- 1986 – Gaël Monfils, French tennis player
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1943 – Charles Atangana, Cameroonian chief (b. 1880)
- 1970 – François Mauriac, French author, Nobel Prize laureate (b. 1885)
- 1988 – Luis Walter Alvarez, American physicist, Nobel Prize laureate (b. 1911)