Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 20 Oṣù Kẹ̀sán

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ọjọ́ 20 Oṣù Kẹ̀sán:

  • 1946 – Ayẹyẹ fíìmù ti Cannes àkọ́kọ́ ti waye, tí àti dá dúró fún ọdún méje nítorí ogún àgbáyé kejì.
  • 1962 – Ọmọ Afíríkà Amẹrika kan tí a pè ní James Meredith, tí ní ìdíwọ́ díẹ̀ láti wọ ilé-ìwé Fásitì ti Mississippi.

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

Àwọn aláìsí lóòní...

  • 1994Abioseh Nicol, olóògùn , ọmọ̀wé, àti aṣojú ìjọba tí orílẹ̀ èdè Sierra Leone (b. 1924)
  • 1996Reuben Kamanga, olóṣèlú orílẹ̀-èdè Zambia, igbá-kejì Ààrẹ alàkọ́kọ́ tí Zambia (b. 1929)
Ọjọ́ míràn: 18 · 19 · 20 · 21 · 22 | ìyókù...