Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 22 Oṣù Kejìlá
Appearance
- 1894 – Ẹjọ́ Dreyfus bere ni France, nigbati Alfred Dreyfus je didalebi esun idote, nitori esin re.
- 1997 – Hussein Farrah Aidid jọ̀wọ́ ìjàkadì ipò bíi Ààrẹ ilẹ̀ Sòmálíà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1887 – Srinivasa Ramanujan, onimo mathimatiki ara India (al. 1920)
- 1960 – Jean-Michel Basquiat, onisona ara Amerika (al. 1988)
- [[]]
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1880 – George Eliot, olukowe ara Ilegeesi (ib. 1819)
- 1989 - Samuel Beckett, olukowe ara Irelandi (ib. 1906).