Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 24 Oṣù Kínní
Ìrísí
- 1862 – Bucharest di olúìlú Romania.
- 1943 – Ogun Àgbáyé 2k: Franklin D. Roosevelt àti Winston Churchill parí ìpàdé ní Casablanca.
- 1986 – Voyager 2 kọjá bíi 81,500 km (50,680 miles) lẹ́gbẹ̀ẹ́ Úránù.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1679 – Christian Wolff, amòye ará Jẹ́mánì (al. 1754)
- 1862 – Edith Wharton, olùkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (al. 1937)
- 1916 – Rafael Caldera, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Venezuela (al. 2009)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1965 – Winston Churchill, Alákóso Àgbà ilẹ̀ Brítánì (ib. 1874)
- 1966 – Homi J. Bhabha, onímọ̀ físíksì ará Índíà (b. 1909)
- 1993 – Thurgood Marshall (fọ́tò), Onídájọ́ Ilé-Ẹjọ́ Gígajùlọ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (ib. 1908)