Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 27 Oṣù Kejì
Ìrísí

- 1844 – Olómìnira Dómíníkì (àsìá) gba ìlómìnira lọ́dọ̀ Haiti.
- 1933 – Ilé aṣòfin Jẹ́mánì ní Berlin, Reichstag, gbaná jẹ.
- 1999 – Olusegun Obasanjo borí ìdìbòyàn fún ààrẹ Nigeria.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1879 – René Lefebvre, martyr of the French Resistance (d. 1944)
- 1902 – John Steinbeck, American writer, Nobel laureate (d. 1968)
- 1913 – Paul Ricoeur, amòye ará Fránsì (al. 2005)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1943 – Kostis Palamas, Greek poet, twice nominated for the Nobel prize (b. 1859)
- 1989 – Konrad Lorenz, Austrian zoologist, recipient of the Nobel Prize in Physiology or Medicine (b. 1903)
- 1998 – George H. Hitchings, American scientist, recipient of the Nobel Prize in Physiology or Medicine (b. 1905)