Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 2 Oṣù Keje
Appearance
- 1561 – Menas, Ọba ilẹ̀ Ethiopia, borí ọ̀tẹ̀ ní Emfraz.
- 1839 – Bíi ogún mẹ̀élì láti etí omi Kúbà, àwọn ẹrú 53 tí Joseph Cinqué ṣ'olórí wọn fipá gba ọkọ̀-ọjúomi Amistad.
- 1964 – Ààrẹ ilẹ̀ Amẹ́ríkà Lyndon B. Johnson fọwọ́sí Ìṣe Òfin àwọn Ẹ̀tọ́ Aráàlú 1964 (àwòrán) tó fòfin dínà ìwà ẹlẹ́yàmẹ̀yà ní àwọn ibi ìgboro.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
ọn
- 1908 – Thurgood Marshall, Adájọ́ ilé ẹjọ́ gígajùlọ Amẹ́ríkà (al. 1993)
- 1925 – Medgar Evers, alákitiyan àwọn ẹ̀tọ́ aráàlú Amẹ́ríkà (al. 1963)
- 1925 – Patrice Lumumba, Alakoso Agba Orileominira Oseluarailu Kongo (al. 1961)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1778 – Jean-Jacques Rousseau, Swiss philosopher (b. 1712)
- 1961 – Ernest Hemingway, American writer, Nobel laureate (b. 1899)
- 1977 – Vladimir Nabokov, Russian-born writer (b. 1899)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |