Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 31 Oṣù Kẹta
Ìrísí
- 1931 – Iwariri-ile fa iparun ilu Managua, Nicaragua, o faku pa eniyan 2,000.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1596 – René Descartes, amoye ara Fransi (al. 1650)
- 1811 – Robert Bunsen, asiseogun ara Jemani (al. 1899)
- 1948 – Al Gore (foto), Igbakeji Aare 45k orile-ede Amerika
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1727 – Isaac Newton, asefisiksi ati onimo matimatiki ara Ilegeesi (ib. 1643)
- 1797 – Olaudah Equiano, asoko-eru omo Igbo (ib.1745)
- 1980 – Jesse Owens, elere idaraya ara Amerika (ib. 1913)