Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 9 Oṣù Kẹrin
Ìrísí
- 1957 – Ìladò Suez ni Egypt je lila, won si si fun awon oko-ojuomi.
- 1968 – Isinku Dr. Martin Luther King, Jr. waye.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1821 – Charles Baudelaire, olukowe ara Fransi (al. 1867)
- 1898 - Paul Robeson (foto), osere ara Amerika (al. 1976)
- 1979 – Keshia Knight Pulliam, osere ara Amerika
Àwọn aláìsí lóòní...
- 436 – Tan Daoji, agbailu ara Shaina
- 1959 – Frank Lloyd Wright, onimo-ipilese ara Amerika (ib. 1867)
- 1999 – Ibrahim Baré Maïnassara, oloselu ara Nijer (ib. 1949)