Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/T Cells
Ìrísí
Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọ̀rọ̀ ìforúkọsílẹ̀
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ẹpẹ̀lẹ́ o ẹ̀yín ẹlẹ́gbẹ́ mi. Ó wùnmí kín máa bá iṣẹ́ ribiribi mi lọ gẹ́gẹ́ bí alámójútó. Lọ́tẹ̀ yíi mó fẹ́ jẹ́ kí alámójútó mi jẹ́ láílái (permanent). Ọ̀gá mi Oníṣe:Demmy nìkan ni alámójútó láílái tí ó wà níbí, ṣùgbọn ọwọ́ wọ́n máa ń dí. Ó dárá kí a pé méjì síbí torí ìdágìrì. Ẹṣeun. T Cells (talk · contribs · email) 18:58, 19 Oṣù Kẹ̀sán 2018 (UTC)
Àwọn ìfi orúkosílẹ̀ fún alámòjútó tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àkókò ìbò
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ètò ìdìbò yí bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ní 08:00:59 18/09/18 tí ó sì ma parí ní 08:00:59 25/08/18.
Ìjíròrò
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Àwọn ìjápọ̀ fún oníṣẹ́ T Cells: T Cells (talk.contribs.deleted.logs.block log.lu.rfar.rfc.rfcu.ssp.spi)
- A lè rí àwọn àtúnṣe tí oníṣẹ́ T Cells ti sọ̀rọ̀níṣókí ní ibí.
Jọ̀wọ́ sọ̀rọ̀ tútù tó dára, pẹ̀lụ́ ìrẹ̀lẹ̀. Tí o kò bá mọ oníṣẹ́ tí ó fẹ́ di alábójútó yìí dáradára, Jọ̀wọ́ ṣe àyẹ̀wo àfikún rẹ̀ dáradára kí o tó dási.
Faramọ́ (support)
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Faramọ́ (support) fún títí láíláí (permanet adminship). T Cells (talk · contribs · email) 18:58, 19 Oṣù Kẹ̀sán 2018 (UTC)
- Faramọ́ (support) fún títí láíláí (permanet adminship).Adefanike (ọ̀rọ̀) 20:35, 19 Oṣù Kẹ̀sán 2018 (UTC)
- Faramọ́ (support) fún títí láíláí (permanet adminship). Oníṣe:Nurudlight 21:13, 19 Oṣù Kẹ̀sán 2018
- Faramọ́ (support) fún títí láíláí (permanent adminship). MaryamOke (ọ̀rọ̀) 03:56, 20 Oṣù Kẹ̀sán 2018 (UTC)
- Faramo fun titi laila (permanent). Arakunrin you je okan gboogi lara awon ti o n moju to Yoruba Wikipedia. Agbalagba (ọ̀rọ̀) 12:06, 29 Oṣù Kẹ̀sán 2018 (UTC)
lòdìsí (oppose)
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìdásí gbogboògbò (general comment)
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]tí àwọn ìforúkosílẹ̀ kó bá dé ojú ìwọ̀n.