Wikipedia:Ẹ mọ́ fòyà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àgbàjọ Wikipedia dá ìmọ̀ràn pé kí ẹ mọ́ fòyà láti ṣàtúnṣe àwọn ojúewé. Wiki yìí yíò gbòòrò dáadáa tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn bá únṣàtúnṣe àwọn àsìṣe yìówù.