Jump to content

Wikipedia:Àwọn alámùójútó

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Wikipedia:Administrators)

Àwọn Alámójútó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti pa ojú ewé kan rẹ́, dínà mọ́ àwọn bàsèjẹ́ kí wọ́n má lè ṣiṣẹ́ mọ́. Bí wọ́n bá sì dínà mọ́ ọ tí o sì fẹ́ kí wọ́n ṣínà tàbí gbà ọ́ wọlé padà, o lè kàn sí alámójútó tó dínà mọ́ ọ lórí ' ìkànì e meèlì rẹ̀ ' tí ó wà ní apá òsì ojú ewé oníṣẹ́ rẹ̀.

Àwọn Alámójútó
Àwọn Alámùójútó tẹ́lẹ̀
  • Freddie Mercury (láti 26 July 2006 sí 13 February 2008)
  • Mark Dingemanse (láti 11 February 2006, ṣugbọn kìí ṣe alamojuto lórí yo.wikipedia mọ́).