Will Poulter
Will Poulter | |
---|---|
Poulter ní Paris tí wọ́n tí sàfihàn The Revenant ní Oṣú kínín ọdún 2016 | |
Ọjọ́ìbí | William Jack Poulter 28 Oṣù Kínní 1993 Hammersmith, London, England, United Kingdom |
Orílẹ̀-èdè | Gẹ̀ẹ́sì |
Iṣẹ́ | Òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 2007–present |
William Jack "Will" Poulter (bíi Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù kínín Ọduń 1993) jẹ́ òṣèré Gẹ̀ẹ́sì. Òhun ni Gally nínú eré tí ó ṣàmúbádọ́gba ìwé ìtàn ọ̀dọ́mọkùnrin kan tí ó bá ara rẹ̀ ní àwùjọ tí kódáranínú nínú eré The Maze Runner ní ọdún 2014 tí ó sì gbà ẹ̀bùn BAFTA Rising Star. Òhun ní Lee Carter nínú eré Son of Rambow (2007),[1] Eustace Scrubb nínú The Chronicles of Narnia: The Voyage of the Dawn Treader (2010), Kenny Rossmore nínú We're the Millers (2013) àti Jim Bridger níń The Revenant (2015).
Igba èwe
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Poulter ní Hammersmith, London, ó jẹ́ ọmọ Caroline (Barrah), tí ó jẹ́ nọ́ọ̀sì tẹ́lẹ̀ àti Neil Poulter, ọ̀jọ̀gbọ́ nínú ìmọ̀ ẹ̀kọ́ ọkàn.[1][2] Wọ́n tọ́ ìyá rẹ̀ nínú ẹbí Gẹ̀ẹ́sì ní orílẹ̀ èdè Kenya, ní ibi tí bàbá rẹ́ ti jẹ́ alabójútó eré ìdárayá. Poulter kàwé ní Harrodian School.[1]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Poulter ti kópa nínú oríṣirisí eré kí ó tó ṣe Lee Carter ní ọdún 2007 nínú eré Son of Rambow tí wọ́n ṣe àtúnyẹ̀wò ẹ, ti ó sì gba oríyìn fún iṣẹ́ Poulter àti ẹlẹgbé rẹ̀ Bill Milner. Ó tún ṣe iṣẹ́ pẹlú àwọ́n òṣèré aláwàdà ní School of Comedy,[3] tí àkọkọ́ iṣé náà dàgbéléwò lóríi Channel 4's Comedy Lab ní Ọjó òkànlelógún Oṣù kẹjọ Odún 2008. School of Comedy nígbà yẹn ṣẹ̀ṣẹ̀ di Channel 4,[4] tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ní di àgbéléwò ní Ọjó kejì Oṣu kẹwá ọdún 2009. Ètò náà parí léyin ìpele kejì.
Ni ọdún 2009, wọ́n yàán lati ṣe Eustace Scrubb nínú eré The Chronicles of Narnia: The Voyage of the Dawn Treader (tí wọ́n wò ní Queensland, Australia), díẹ̀ nínú àwọ́n èbí rẹ́ tẹ̀lé. Eré náa kókó di wíwò ní Ọjọ́ kẹwá Oṣu kejìlá ọ́dún 2010. Eré yìí di àtúnyẹ̀wò sùgbọ́n wọn gba iṣé Poulter tọwọ́tẹsẹ̀.[5][6][7]
Àwọn eré tí ó ti kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Eré | Ipa | Àwọn àkíyèsí |
---|---|---|---|
2007 | Son of Rambow | Lee Carter | |
2010 | The Chronicles of Narnia: The Voyage of the Dawn Treader | Eustace Scrubb | |
2012 | Wild Bill | Dean | |
2013 | We're the Millers | Kenny Rossmore | |
2014 | Plastic | Fordy | |
The Maze Runner | Gally | ||
A Plea for Grimsby | Jone | Short film | |
Glassland | Shane | ||
2015 | The Revenant | Jim Bridger | |
2016 | Kids in Love | Jack | Post-production |
War Machine | Ortega | Post-production | |
2017 | Maze Runner: The Death Cure | Gally | Filming |
Àwọn amóhùnmáwòran tí ó ti kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa | Àwọ́n àkíyèsí |
---|---|---|---|
2007 | Comedy: Shuffle | Find Your Folks Presenter | |
2008 | Comedy Lab | Various | |
Lead Balloon | Sweet Throwing Boy | ||
2009–2010 | School of Comedy | Various | |
2010 | The Fades | Mac | Pilot |
Àwọn ohùn tí ó ti kópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọ́lé | Ipa | Àwọn àkíyèsí |
---|---|---|---|
2015 | The Incredible True Story | Christopher Smith | Album |
Èbún àti yíyàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 Son of Rambow: ready for action at www.telegraph.co.uk (accessed 22 June 2008)
- ↑ http://www.scotsman.com/the-scotsman-2-7475/scotland/interview-will-poulter-actor-1-2195933
- ↑ Lee, Robin (16 August 2007). "School of Comedy". The List. http://edinburghfestival.list.co.uk/article/3954-school-of-comedy. Retrieved 24 January 2014.
- ↑ "Comedy Labs on Channel 4".
- ↑ Will Poulter Cast as Eustace Scrubb Archived 2009-01-13 at the Wayback Machine. at www.narniaweb.com (accessed 22 June 2008)
- ↑ It's luvverly Cockney sparra Keira at www.dailymail.co.uk (accessed 22 June 2008
- ↑ Will Poulter Cast in Narnia 3 Archived 2013-10-29 at the Wayback Machine. at www.comingsoon.net (accessed 22 June 2008