Jump to content

William Adams

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
William Adams
(1564-1620)Names:
Christian name: William Adams
Japanese name: Miura Anjin (三浦按針)
Dates:
Birth: (1564-09-24)Oṣù Kẹ̀sán 24, 1564
Gillingham, Kent, England
Death: May 16, 1620(1620-05-16) (ọmọ ọdún 55)
Hirado, Kyūshū, Japan

William Adams Wọ́n bí Adams ní 1564. Ó kú ní 1620. Iṣẹ́ ọkọ̀ ojú omi (navigation) ni ó ń ṣe. Dillingham, Kent ni wọ́n ti bí i ní ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì. Òun ni ọmọ ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì àkọ́kọ́ tí yóò lọ sí Japan. Shogun Ieyasu ní ìfẹ́ sí i gidi ni, nítorí ìdí èyí, wọn fi ibi tí àwọn Gẹ̀ẹ́sì àti Dutch ti lè máa ṣòwò lélẹ̀ ní Japan. Eléyìí sì wà títí di 1616.