William Bliss Baker
William Bliss Baker | |
---|---|
Fallen Monarchs by Baker | |
Ilẹ̀abínibí | American |
Pápá | Painting |
Training | M.F.H. de Haas Albert Bierstadt[1] |
Movement | |
Iṣẹ́ | Fallen Monarchs Morning After the Snow |
Ẹ̀bùn | Elliott Prize for Drawing (1879) Hallgarten Prize (1885) |
William Bliss Baker (Ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kọkànlá ọdún 1859 – Ogúnjọ́ oṣù kọkànlá ọdún 1886) jẹ́ ọmọ bíbí Ìlú Amẹ́ríkà, tí ó jẹ́ oníṣẹ́ ọnà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ọnà ṣíṣe ní àkóko tí Ilé Ìwé Hudson River ń kó'gbà wọ'lé. Baker bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ọdún 1876 ní National Academy of Design, níbi tí ó ti kọ́ ẹ̀kó pẹ̀lú Bierstadt àti de Haas. Lẹ́yìn èyí, ó dá ilé iṣé ọnà sílẹ̀ ní Clifton Park, New York; àti New York City, níbi tí ó ti ń ṣe iṣẹ́ ọnà pẹ̀lú ọ̀dà àti àwọn àwọ̀ olómi lóríṣiríṣi. Ó lé ní àádóje iṣé ọnà tí Baker ṣe parí, tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ sì wà ní àwọ̀ dúdú àti funfun.
Nígbà tí ó di ẹni ọdún mẹ́rin-dín-lọ́gbọ̀n, Baker tí ó ṣẹ̀ṣè bẹ̀rẹ̀ sì di gbajú-gbajà oníṣé ọnà tí ọ́́ fer̀an láti máa ya aworan ayika ku ni ile baba re ni Hoosick Falls, New York. Iwe Iroyin New York Times salaye wipe iku re "ti mu kí ìlú Amẹ́ríkà pàdànú ọ̀kan lára àwọn oníṣẹ́ ọnà tí ọjọ́ ọ̀la rẹ̀ dára."
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Bentley, Edward P. "BAKER, WILLIAM BLISS American 1859 - 1886". Archived from the original on May 29, 2013. Retrieved April 20, 2007.
- ↑ Jones, Agnes Halsey (1968). "Introduction—The Hudson River School". Hudson River School. Geneseo, New York, United States: W. F. Humphrey Press. pp. 1–9, 16-17.