Worknesh Degefa
Ìrísí
Worknesh Degefa near the halfway point of the 2019 Boston Marathon, which she won. | ||||||||||
Òrọ̀ ẹni | ||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́ | Worknesh Degefa | |||||||||
Ọjọ́ìbí | 28 Oṣù Kẹ̀wá 1990 Ethiopia | |||||||||
Sport | ||||||||||
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia | |||||||||
Erẹ́ìdárayá | Sport of athletics | |||||||||
Event(s) | Marathon, half marathon | |||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Worknesh Degefa tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n, oṣù kẹwàá, ọdún 1990 jẹ́ ọmọbìnrin tó ń kópa ní nú eré sísá ti ọ̀nà jínjìn ní orílẹ̀-èdè Ethopia.[1] Arábìnrin náà jẹ́ ẹlẹ́ẹ̀kẹrin nínú àwọn tó lè sá eré jù.
Àṣeyọrí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2016, Worknesh kópa nínú Marathon ti ìdajì ti Prague, tó sì parí láàárín wákàtí 1:06:14[2]. Ní ọdún 2017, Degefa kópa nínu Marathon ti Dubai pẹ̀lú wákàtí 2:19:53. Ní oṣù January, ọdún 2019, Worknesh kópa nínú Marathon ti Dubai pẹ̀lú wákàtí 2:17:41[3]. Ní ọjọ́ karùnlélógún oṣù April, ọdún 2019, Degefa yege nínú Marathon ti Boston pẹ̀lú wákàtí 2:23:31[4].