Wum

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Wum
CountryFlag of Cameroon.svg Cameroon
ProvinceNorthwest Province
Population
 (2007)
 • Total75,582 (est)

Wum je ilu ni Kamẹroon

Apa ariwa Cameroon ni ibùgbé àwọn ènìyàn Wum. Wọ́n jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjìlá ènìyàn níye. Àwọn alábágbé wọn ni Esu, kom àti Bafut. Èdè Wum (macro-Bantu) ni wọ́n n sọ. Nítori ìgbàgbọ̀ wọn nipa orí, kò fẹ̣́si nínú isẹ́ ọnà wọn tí a kì í rì àwòrán ori. Àgbè ọlọ́gìn àgbàdo, isu, ati ewébe ni àwọn ará Wum. Wọn tún jẹ́ olùsìn adìẹ ati ewúrẹ́ èyí sì kó ìpa tó jọjú nínú àtijẹ wọn lójojúmọ́. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Fulani ló di mùsùlùmí ni òpin ẹgbẹru ọdun méjìdínlógún. Akitiyan wọn nínú ẹ̀sìn yìí láti tàn-án ka ló mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ará Wum dí ẹlẹ́sìn mùsùlùmí.

Àwọn Akóìjánupọ̀: 6°23′N 10°04′E / 6.383°N 10.067°E / 6.383; 10.067