Yẹmí Ayébọ̀
Ìrísí
Yẹmí Ayébọ̀ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Yẹmí My Lover jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé òun sinimá, ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Òndó. [1]
Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà ní ọdún 1983, lásìkò tí ó wà ní ilé-ẹ̀kọ́ oníwé Mẹ́wá, tí ó sì ko pa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré sinimá àgbéléwò Yorùbá.[2] Eré sinimá tí ó gbe jáde ní àsìkò ọdún 1990s ni Yẹmí My Lover tí ó sì padà di orúkọ orí ìtàgé rẹ̀ títí dòní.[3]
Àwọn eré sinimá rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lára àwọn eré tí ó ti gbe jáde ni
- Yẹmí My Lover
- Yẹmí in the Moon
- Má danwò àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Why I don’t do stunts in movies any more----Yemi Ayebo, aka Yemi My Lover". Nigeria Films. 2016-03-24. Retrieved 2020-01-29.
- ↑ "I’ve made movies bigger than Yemi my Lover – Ayebo – Punch Newspapers". Punch Newspaper. 2019-06-15. Retrieved 2020-01-29.
- ↑ "Yemi my lover (VHS tape, 1990) [WorldCat.org]". WorldCat.org. 1999-02-22. Retrieved 2020-01-29.