Jump to content

Yam pepper soup

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Yam pepper soup jẹ́ oúnjẹ Nàìjíríà tí à ń iṣu puna ṣe. Ó ṣe pàtàkì kí iṣu náà rọ̀.[1][2]

Ọbẹ̀ náà wọ́pọ̀ ni ìhà Gúsù Ìlà-Oòrùn ti Nàìjíríà àti pé díè lára àwọn èròjà ọbẹ̀ yìí ni ehuru, ṣọ̀mbọ̀, oríṣiríṣi ẹran, iyọ̀ àti efinrin.[3][4]

Àwọn èròjà yìí ni ẹ ma fi si nígbà tí iṣu náà bá rọ̀ tí ó sì ti ń di àsáró.[5]

Àwọn oúnjẹ mìíràn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ẹ lè fi Yam pepper soup jẹ ìrẹsì àti dòdò.[6]

  • Igbo Cuisine
  • Ogbono soup
  • Nigeria cuisine
  • Peanut soup

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "How To Make Nigerian Yam Pepper Soup". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-12. Archived from the original on 2022-05-07. Retrieved 2022-06-30. 
  2. Natural, Sympli (2019-02-16). "Yam and Goat Meat Pepper Soup". Medium (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30. 
  3. omotolani (2018-03-06). "How to cook Nigerian yam pepper soup". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30. 
  4. a, temitope (2016-09-02). "How to make yam peppersoup". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-06-30. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  5. "Yam pepper soup delight". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-18. Retrieved 2022-06-30. 
  6. "Yam and Goat Meat Pepper Soup". Daily Trust (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-03-21. Retrieved 2022-06-30.