Yemisi Edun
Ìrísí
Yemisi Edun | |
---|---|
Ádárì àgbà First City Monument Bank | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 13 July 2021 | |
Asíwájú | Adam Nuhu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Education | |
Profession | Banker |
Yemisi Edun ni adari àgbà ile ifowopamosi ti First City Monument Bank(FCMB), òun ni obinrin akoko ti o di ipò náà mú. A yàn sípò náà ní 13 July 2021 léyìn ìgbà tí Adam Nuhu fi ipo náà sílè nitori èsùn biba ìyàwó elomiran sun tí a fi kan.[1] Yemisi jé omobibi ìpínlè Èkó.
Èkó rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Yemisi Edun gba àmì-èye Bachelor's Degree nínú imo Chemistry ní Yunifásitì ti ilé ìfé. O tún tèsíwájú ní yunifásitì ti Liverpool, níbi ti ó ti gba master's degree ní International accounting and finance.[2]
Isé rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]O bèrè ise gégé bi onibojuto owo ilé-isé Akintola Williams and Co. ni odun 1987, o padà di alakoso agba ilé-isé náà koto dipe ó darapo mó ilé ifowopamosi tí FCMB ní odun 2000. Ó jé adari àgbà ní èka owó koto dipe wón yan sípò adari àgbà gbogbo ilé ifowopamosi náà.
Àwon ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Adamolekun, Ronald (2021-07-13). "FCMB appoints Yemisi Edun to replace Adam Nuru as CEO". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-05-28.
- ↑ "Mrs. Yemisi Edun - Managing Director". First City Monument Bank. Retrieved 2022-05-28.