Jump to content

Yinka Olukunga

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Yinka Olukunga
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • Actress
Gbajúmọ̀ fúnNnenna and friends

Yínká Olukunga, tí orúkọ àbísọ rẹ̀ jẹ́ Ọláyínká Olukunga, tí a sì mọ̀ sí Nnenna, jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àti olùgbàlejò lóri ètò tẹlifíṣọ̀nù.

Iṣẹ́ ìṣe rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó jẹ́ akẹ́ẹ̀kọ́-gboyè láti Yunifásitì ti Ìpínlẹ̀ Èkó, ó sì gbajúmọ̀ fún ètò tẹlifíṣọ̀nù àwọn ọmọdé tí ó maá n ṣe lọ́pọ̀lọpọ̀ fún ilé-iṣẹ́ Wálé Adénúgà . Ó ti sọ ńipa iṣẹ́ ìṣe rẹ̀ pé: "Ṣíṣẹpọ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọdé maá n fún òun ní ìdùnnú, bẹ́ẹ̀ sì ni rírí wọn nínu ẹ̀wù ẹ̀rín maá n dá òun lárayá."[1]

Ó ṣe ìgbeyàwó ní ọdún 2014, ó sì ti bí àwọn ọmọbìnrin ìbejì tí orúkọ wọ́n jẹ́ Olivia ati Maia ní 18 Oṣù Kẹẹ̀sán, Ọdún 2015.[2][3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "My project can’t make me take other jobs". The Nation. http://thenationonlineng.net/project-cant-make-take-jobs-yinka-olukunga-k-nnenna/. Retrieved 8 October 2016. 
  2. "‘Nnenna and Friends’ Star Actress Yinka Olukunga Shares Beautiful Photos Of Her Family". Motherhood in Style. 21 September 2016. Retrieved 8 October 2016. 
  3. "’My pregnancy was complicated’ – Mother of twins, Nnenna (Yinka Olukunga) denies marrying secretly". Encomium. Retrieved 8 October 2016.