Yoshio Nishina

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Yoshio Nishina, 1926 at Copenhagen

Yoshio Nishina (仁科 芳雄 Nishina Yoshio?, December 6, 1890 – January 10, 1951) lo je baba apilese iwadi fisiksi odeoni ni Japan. O se ajoda afida Klein–Nishina. O je oluwadi akoko RIKEN be sini o je oluko opo awon onimo fisiksi ti ninu won je awon Elebun Nobel meji: Hideki Yukawa ati Sin-Itiro Tomonaga. Nigba Ogun Agbaye 2k o je olori eto atomu Japan. Koto Nishina ni oju osupo gba oruko re.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]