Jump to content

Yunifásítì ìlú Màídúgùri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ọgbà Yunifásítì Maiduguri
Yunifásítì ìlú Màídúgùri

Yunifásítì ìlú Màídúgùri jé yunifásítì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, tí ó wà ní ìlú MaiduguriIpinle Borno. A da kalè(pèlú àwon yunifásitì mefa miran) ni odun 1975 [1], olori yunifásitì náà ni òjògbón Aliyu Shugaba [2]



Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "History". Unimaid, Centre for Distance Learning. 2019-02-06. Archived from the original on 2022-03-05. Retrieved 2022-03-05. 
  2. "Shugaba’s one year as VC Unimaid". Blueprint Newspapers Limited. 2020-07-30. Retrieved 2022-03-05.