Jump to content

Yunifásitì Adekunle Ajasin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Yunifásitì Adekunle Ajasin
Adekunle Ajasin University Akugba Akoko main gate.jpg
MottoFor Learning and Service
EstablishedDecember 1999; ọdún 24 sẹ́yìn (December 1999)
TypePublic
Vice-ChancellorOlugbenga E. Ige
Studentsover 20,000
LocationAkungba-Akoko, Ìpínlẹ̀ Ondo, Nàìjíríà
7°28′45″N 5°44′54″E / 7.479234°N 5.748411°E / 7.479234; 5.748411Coordinates: 7°28′45″N 5°44′54″E / 7.479234°N 5.748411°E / 7.479234; 5.748411
Websiteaaua.edu.ng/
Senate building ti Yunifásitì Adekunle Ajasin ní Akungba Akoko, Ìpínlè Ondo. 04

Yunifásitì Adekunle Ajasin, Akungba-Akoko (AAUA) jẹ́ ọ̀kan lára àwọn Yunifásitì ìjọba ìpínlè Ondo.[1] Yunifásitì náà wà ní Akungba Akoko, Ìpínlẹ̀ Òndó, Nàìjíríà.

Ìjọba ìpínlè Ondo kókó dá Yunifásitì Adekunle Ajasin kalè gẹ́gẹ́ bi Yunifásítì Obafemi Awolowo ní ọdún 1982, adarí Yunifásitì náà nígbà yẹn ni Olóyè Michael Adekunle Ajasin.[2] Ìjọba ológun tí ó tẹ́le yí orúkọ Yunifásitì náà dà sí Yunifásitì ìpínlè Ondo ní ọdun 1985.

  1. "Adekunle Ajasin University Akungba | www.aaua.edu.ng". www.myschoolgist.com.ng. Retrieved 2016-03-23. 
  2. "Adekunle Ajasin University – …21st Century University, properly called!" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-05-11. Retrieved 2020-05-28.