Jump to content

Yusuf Isah Kurdula

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Yusuf Isah Kurdula je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà to je ọmọ ile ìgbìmọ̀ asoju-sofin, to n ṣoju àgbègbè Gudu / Tangaza ti Ìpínlẹ̀ Sokoto ni ile ìgbìmọ̀ aṣojú orile-ede kẹsàn-án. Wọ́n yàn án lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú All Progressives Congress (APC), lọ́dún 2019. [1] [2] [3]