Yusuf Lule

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Yusuf Lule
4th President of Uganda
In office
13 April 1979 – 20 June 1979
AsíwájúIdi Amin
Arọ́pòGodfrey Binaisa
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Yusuf Kironde Lule

10 April 1912
Kampala, Uganda Protectorate
Aláìsí21 January 1985 (aged 72)
London, United Kingdom

Yusuf Kironde Lule (10 April 1912 – 21 January 1985) fìgbà kan jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ti orílẹ̀-èdè Uganda, àti òṣìṣẹ́ ìjọba tó sìn gẹ́gẹ́ bí i ààrẹ Uganda kẹrin láàárín oṣù kẹrin àti oṣù kẹfà ọdún.

Ìgbésí ayé rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Yusuf Lule ní 10 Aprilm ọdún 1912 ní Kampala.[1] Ó kàwé ní King's College Budo (1929–34), Makerere University College, Kampala, ní ọdún (1934–36), Fort Hare University ní Alice, South Africa (1936–39) àti ní University of Edinburgh.[2] Ẹlésìn Mùsùlùmí ni tẹ́lẹ̀ kí ó tó gbẹ̀sìn Kìrìsìtẹ́ẹ́nì nígbà tó wà ní King's College Budo.[3]

Ní ọdún 1947, Lule fẹ́ Hannah Namuli Wamala ní ilé-ìjọsìn Kings College Budo, níbi tí ó ti ṣiṣẹ́ bí i olùkọ́, tí arábìrin náà sì jẹ́ olórí àwọn obìnrin.[4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Lule, K. Yusufu", Africa Who's Who, London: Africa Journal for Africa Books Ltd, 1981, p. 636.
  2. "Uncovering University of Edinburgh's black history". 30 April 2021. 
  3. Mubangizi, Michael (11 January 2012). "They stand tall in new found faith". The Observer. Archived from the original on 15 August 2021. https://web.archive.org/web/20210815235417/https://observer.ug/lifestyle/sizzling-faith/16612-they-stand-tall-in-new-found-faith. 
  4. Okech, Jennifer A. (5 June 2011). "Farewell to Hannah Namuli Lule". Daily Monitor. Retrieved 5 April 2020.